Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá lọ sọ fún Saulu pé, “Àwọn eniyan ń dẹ́ṣẹ̀ sí OLUWA nítorí wọ́n ń jẹ ẹran tẹ̀jẹ̀tẹ̀jẹ̀.”Saulu bá wí pé, “Ìwà ọ̀dàlẹ̀ ni ẹ hù yìí. Ẹ yí òkúta ńlá kan wá sọ́dọ̀ mi níhìn-ín.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:33 ni o tọ