Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Heberu tí wọ́n ti wà lẹ́yìn àwọn ará Filistia tẹ́lẹ̀, tí wọ́n sì bá wọn lọ sí ibùdó ogun wọn, yipada kúrò lẹ́yìn wọn, wọ́n sì dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun Israẹli tí wọ́n wà pẹlu Saulu ati Jonatani.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:21 ni o tọ