Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Filistia kó ara wọn jọ láti bá Israẹli jagun. Wọ́n ní ẹgbaa mẹẹdogun (30,000) kẹ̀kẹ́ ogun, ati ẹgbaata (6,000) ẹlẹ́ṣin, àwọn ọmọ ogun wọn sì pọ̀ bí eṣú. Wọ́n lọ sí Mikimaṣi ní ìhà ìlà oòrùn Betafeni, wọ́n pàgọ́ wọn sibẹ.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 13

Wo Samuẹli Kinni 13:5 ni o tọ