Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 13:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli bá wí fún un pé, “Ìwà òmùgọ̀ patapata gbáà ni èyí. O kò pa òfin tí OLUWA Ọlọrun rẹ fún ọ mọ́. Bí ó bá jẹ́ pé o gbọ́ tirẹ̀ ni, nisinsinyii ni OLUWA ìbá fìdí ìjọba rẹ múlẹ̀ lórí Israẹli títí lae.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 13

Wo Samuẹli Kinni 13:13 ni o tọ