Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 13:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Samuẹli wí fún un pé, “Kí lo dánwò yìí?” Saulu bá dá a lóhùn pé, “Àwọn eniyan náà ti bẹ̀rẹ̀ sí sá kúrò lẹ́yìn mi, o kò sì dé ní àkókò tí o dá. Àwọn ará Filistia sì ti kó ara wọn jọ ní Mikimaṣi.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 13

Wo Samuẹli Kinni 13:11 ni o tọ