Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli dáhùn pé, “OLUWA ati ọba, ẹni àmì òróró rẹ̀ ni ẹlẹ́rìí lónìí pé, ẹ gbà pé ọwọ́ mi mọ́ patapata.”Àwọn eniyan náà dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, OLUWA ni ẹlẹri wa.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 12

Wo Samuẹli Kinni 12:5 ni o tọ