Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 12:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa bẹ̀rù OLUWA, kí ẹ sì máa sìn ín pẹlu gbogbo ọkàn yín. Ẹ ranti àwọn nǹkan ńláńlá tí ó ti ṣe fun yín.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 12

Wo Samuẹli Kinni 12:24 ni o tọ