Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 12:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii, ọba ni yóo máa ṣe olórí yín. Ní tèmi, mo ti dàgbà, ogbó sì ti dé sí mi. Àwọn ọmọ mi sì ń bẹ lọ́dọ̀ yín. Láti ìgbà èwe mi ni mo ti jẹ́ olórí fun yín títí di àkókò yìí.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 12

Wo Samuẹli Kinni 12:2 ni o tọ