Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àgbààgbà Jabeṣi dáhùn pé, “Fún wa ní ọjọ́ meje, kí á lè ranṣẹ jákèjádò ilẹ̀ Israẹli. Bí kò bá sí ẹni tí yóo gbà wá, a óo jọ̀wọ́ ara wa fún ọ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 11

Wo Samuẹli Kinni 11:3 ni o tọ