Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 11:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òwúrọ̀ kutukutu ọjọ́ keji, Saulu pín àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sí ọ̀nà mẹta, wọ́n kọlu ibùdó àwọn ọ̀tá wọn, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí pa wọ́n títí di ọ̀sán ọjọ́ náà. Àwọn tí kò kú lára wọn fọ́nká, tóbẹ́ẹ̀ tí kò fi sí eniyan meji tí wọ́n dúró papọ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 11

Wo Samuẹli Kinni 11:11 ni o tọ