Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 10:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Máa lọ sí Giligali ṣiwaju mi. N óo wá bá ọ níbẹ̀ láti rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia. Dúró níbẹ̀ fún ọjọ́ meje, títí tí n óo fi dé, n óo sì sọ ohun tí o óo ṣe fún ọ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 10

Wo Samuẹli Kinni 10:8 ni o tọ