Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 10:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà, ẹ̀mí OLUWA yóo bà lé ọ, o óo sì darapọ̀ mọ́ wọn, o óo sì máa sọ àsọtẹ́lẹ̀, o óo sì yàtọ̀ patapata sí bí o ti wà tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 10

Wo Samuẹli Kinni 10:6 ni o tọ