Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 10:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli ṣe àlàyé àwọn ẹ̀tọ́ ati iṣẹ́ ọba fún àwọn eniyan náà. Ó kọ àwọn àlàyé náà sinu ìwé kan, ó sì gbé e siwaju OLUWA. Lẹ́yìn náà, ó ní kí olukuluku máa lọ sí ilé rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 10

Wo Samuẹli Kinni 10:25 ni o tọ