Wọ́n bi OLUWA pé, “Àbí ọkunrin náà kò wá ni?”OLUWA dá wọn lóhùn pé, “Ó ti farapamọ́ sí ààrin àwọn ẹrù.”