Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 1:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó gba ọmú lẹ́nu rẹ̀, ó mú un lọ́wọ́ lọ sí Ṣilo. Nígbà tí ó ń lọ, ó mú akọ mààlúù ọlọ́dún mẹta kan lọ́wọ́, ati ìyẹ̀fun ìwọ̀n efa kan, ati ọtí waini ẹ̀kún ìgò aláwọ kan. Ó sì mú Samuẹli lọ sí Ṣilo ní ilé OLUWA, ọmọde ni Samuẹli nígbà náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 1

Wo Samuẹli Kinni 1:24 ni o tọ