Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 1:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, àkókò tó fún Elikana ati ìdílé rẹ̀ láti lọ sí Ṣilo, láti lọ rú ẹbọ ọdọọdún, kí Elikana sì san ẹ̀jẹ́ tí ó jẹ́ fún OLUWA.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 1

Wo Samuẹli Kinni 1:21 ni o tọ