Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Hana ń gbadura ninu ọkàn rẹ̀, kìkì ètè rẹ̀ nìkan ní ń mì, ẹnikẹ́ni kò gbọ́ ohun tí ó ń sọ. Nítorí náà, Eli rò pé ó ti mu ọtí yó ni.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 1

Wo Samuẹli Kinni 1:13 ni o tọ