Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Hana bá OLUWA jẹ́jẹ̀ẹ́ ó ní, “OLUWA àwọn ọmọ ogun, bí o bá ṣíjú wo ìyà tí èmi iranṣẹ rẹ ń jẹ, tí o kò gbàgbé mi, tí o fún mi ní ọmọkunrin kan, n óo ya ọmọ náà sọ́tọ̀ fún ìwọ OLUWA ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, abẹ kò sì ní kàn án lórí.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 1

Wo Samuẹli Kinni 1:11 ni o tọ