Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 8:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá kọ́ àgọ́ àwọn ọmọ ogun kan sí Aramu, ní Damasku, gbogbo àwọn ará Siria sì ń sin Dafidi, wọ́n sì ń san owó ìṣákọ́lẹ̀ fún un. OLUWA fún Dafidi ní ìṣẹ́gun ní gbogbo ibi tí ó lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 8

Wo Samuẹli Keji 8:6 ni o tọ