Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 8:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi sì tún ṣẹgun Hadadeseri, ọmọ Rehobu, ọba Soba, bí ó tí ń lọ láti fi ìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ ní ilẹ̀ tí ó wà ní agbègbè odò Yufurate.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 8

Wo Samuẹli Keji 8:3 ni o tọ