Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

ó rán Joramu ọmọ rẹ̀ láti kí Dafidi ọba kú oríire, fún ìṣẹ́gun rẹ̀ lórí Hadadeseri, nítorí pé Hadadeseri ti bá Toi jagun ní ọpọlọpọ ìgbà. Joramu mú ọpọlọpọ ẹ̀bùn tí wọ́n fi wúrà ṣe, ati ti fadaka, ati ti idẹ lọ́wọ́ fún Dafidi.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 8

Wo Samuẹli Keji 8:10 ni o tọ