Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 7:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu gbogbo bí mo ti ṣe ń bá àwọn ọmọ Israẹli kiri, ǹjẹ́ mo bèèrè lọ́wọ́ ọ̀kan ninu àwọn olórí wọn tí mo yàn láti jẹ́ alákòóso àwọn eniyan mi, pé, Kí ló dé tí wọn kò fi igi kedari kọ́ ilé fún mi?’

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 7

Wo Samuẹli Keji 7:7 ni o tọ