Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 7:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Mò ń bẹ̀bẹ̀ pé kí o bukun arọmọdọmọ mi, kí wọ́n lè máa bá ojurere rẹ pàdé nígbà gbogbo. Ìwọ OLUWA Ọlọrun ni o ṣèlérí yìí, ibukun rẹ yóo sì máa wà lórí arọmọdọmọ mi títí laelae.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 7

Wo Samuẹli Keji 7:29 ni o tọ