Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 7:27 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli, pẹlu ìgboyà ni mo fi gbadura mi yìí sí ọ, nítorí pé o ti fi gbogbo nǹkan wọnyi han èmi iranṣẹ rẹ, o sì ti ṣèlérí pé o óo sọ ìdílé mi di ìdílé ńlá.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 7

Wo Samuẹli Keji 7:27 ni o tọ