Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ọba bá wọlé, ó jókòó níwájú OLUWA, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí gbadura pé, “Ìwọ OLUWA Ọlọrun! Kí ni mo jẹ́, kí ni ilé mi jámọ́ tí o fi gbé mi dé ipò yìí?

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 7

Wo Samuẹli Keji 7:18 ni o tọ