Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 6:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi dá a lóhùn pé, “Ijó ni mò ń jó, níwájú OLUWA tí ó yàn mí dípò baba rẹ ati gbogbo ìdílé rẹ̀, láti fi mí ṣe alákòóso Israẹli, àwọn eniyan OLUWA. N óo tún máa jó níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 6

Wo Samuẹli Keji 6:21 ni o tọ