Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 6:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn rẹ̀ bá yipada, ó pinnu pé òun kò ní gbé e lọ sí Jerusalẹmu, ìlú Dafidi mọ́. Dípò bẹ́ẹ̀, ó gbé e lọ sí ilé Obedi Edomu, ará ìlú Gati.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 6

Wo Samuẹli Keji 6:10 ni o tọ