Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí Dafidi ti ṣẹgun ìlú olódi náà, ó ń gbé inú rẹ̀, ó sì yí orúkọ ibẹ̀ pada sí “Ìlú Dafidi”. Ó kọ́ ìlú náà yíká, bẹ̀rẹ̀ láti Milo, níbi tí wọ́n ti kún ilẹ̀ ní ìhà ìwọ̀ oòrùn òkè náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 5

Wo Samuẹli Keji 5:9 ni o tọ