Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, Rekabu ati Baana, àwọn ọmọ Rimoni ará Beeroti, gbéra, wọ́n lọ sí ilé Iṣiboṣẹti, wọ́n débẹ̀ ní ọwọ́ ọ̀sán, ní àkókò tí Iṣiboṣẹti ń sun oorun ọ̀sán lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 4

Wo Samuẹli Keji 4:5 ni o tọ