Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Báwo ni yóo ti burú tó fún àwọn ẹni ibi, tí wọ́n pa aláìṣẹ̀ sórí ibùsùn ninu ilé rẹ̀? Ṣé n kò ní gbẹ̀san pípa tí ẹ pa á lára yín, kí n sì pa yín rẹ́ kúrò lórí ilẹ̀ ayé?”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 4

Wo Samuẹli Keji 4:11 ni o tọ