Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 3:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn eniyan ṣe akiyesi ohun tí ọba ṣe yìí, ó sì dùn mọ́ wọn. Gbogbo ohun tí ọba ṣe patapata ni ó dùn mọ́ àwọn eniyan.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 3

Wo Samuẹli Keji 3:36 ni o tọ