Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 3:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Abineri pada dé Heburoni, Joabu mú un lọ sí kọ̀rọ̀ kan, níbi ẹnubodè, bí ẹni pé ó fẹ́ bá a sọ ọ̀rọ̀ àṣírí, Joabu bá fi nǹkan gún un ní ikùn. Bẹ́ẹ̀ ni Abineri ṣe kú, nítorí pé ó pa Asaheli arakunrin Joabu.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 3

Wo Samuẹli Keji 3:27 ni o tọ