Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 24:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ pẹpẹ kan sibẹ fún OLUWA, ó sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia. OLUWA gbọ́ adura rẹ̀ lórí ilẹ̀ náà, àjàkálẹ̀ àrùn náà sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ Israẹli.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 24

Wo Samuẹli Keji 24:25 ni o tọ