Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 24:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi dá Gadi lóhùn pé, “Ìdààmú ńlá ni ó dé bá mi yìí, ṣugbọn ó yá mi lára kí OLUWA jẹ wá níyà ju pé kí ó fi mí lé eniyan lọ́wọ́ lọ; nítorí pé, aláàánú ni OLUWA.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 24

Wo Samuẹli Keji 24:14 ni o tọ