Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 23:37-39 BIBELI MIMỌ (BM)

37. Seleki, ará Amoni, Naharai, ará Beeroti, tí ó máa ń ru ihamọra Joabu, ọmọ Seruaya.

38. Ira ati Garebu, àwọn mejeeji jẹ́ ará Itiri;

39. ati Uraya, ará Hiti.Gbogbo àwọn tí wọ́n jẹ́ akọni ọmọ ogun náà jẹ́ mẹtadinlogoji.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23