Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 23:29-31 BIBELI MIMỌ (BM)

29. Helebu, ọmọ Baana, tí òun náà jẹ́ ará Netofa, ati Itai, ọmọ Ribai, ará Gibea, láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini;

30. Bẹnaya ará Piratoni ati Hidai ará ẹ̀bá àwọn odò Gaaṣi;

31. Abialiboni ará Araba, ati Asimafeti ará Bahurimu;

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23