Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 23:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹnaya, ọmọ Jehoiada, ará Kabiseeli, náà tún jẹ́ akọni ọmọ ogun, ọpọlọpọ nǹkan ńláńlá ni ó fi ìgboyà ṣe. Ó pa àwọn akikanju ọmọ ogun ará Moabu meji ní àkókò kan. Ní ọjọ́ kan lẹ́yìn tí yìnyín bọ́ sílẹ̀, ó wọ inú ihò kan lọ, ó sì pa kinniun kan sibẹ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23

Wo Samuẹli Keji 23:20 ni o tọ