Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 23:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnìkẹta ninu àwọn akọni náà ni Ṣama, ọmọ Agee, ará Harari. Ní àkókò kan, àwọn ará Filistia kó ara wọn jọ sí Lehi, níbi tí oko ewébẹ̀ kan wà. Àwọn ọmọ ogun Israẹli sá fún àwọn ará Filistia,

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23

Wo Samuẹli Keji 23:11 ni o tọ