Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 23:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ ìkẹyìn Dafidi nìyí; àní, ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ Dafidi, ọmọ Jese, tí a gbé ga ní Israẹli, ẹni àmì òróró Ọlọrun Jakọbu, olórin dídùn ní Israẹli:

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23

Wo Samuẹli Keji 23:1 ni o tọ