Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 22:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun mi, àpáta mi,ọ̀dọ̀ ẹni tí mo sá pamọ́ sí.Àpáta mi ati ìgbàlà mi,ààbò mi ati ibi ìpamọ́ mi,olùgbàlà mi, ìwọ ni o gbà mí lọ́wọ́ ìwà ipá.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 22

Wo Samuẹli Keji 22:3 ni o tọ