Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 21:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, fún wa ní meje ninu àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin, kí á lè so wọ́n kọ́ níwájú OLUWA ní Gibea, ní orí òkè OLUWA.”Dafidi dáhùn pé, “N óo kó wọn lé yín lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:6 ni o tọ