Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 21:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun mìíràn tún bẹ́ sílẹ̀ ní Gati. Òmìrán kan wà níbẹ̀ tí ó fẹ́ràn ogun jíjà pupọ, ìka mẹfa mẹfa ni ó ní ní ọwọ́ kọ̀ọ̀kan, ati ẹsẹ̀ kọ̀ọ̀kan; ìka ọwọ́ ati ti ẹsẹ̀ rẹ̀ jẹ́ mẹrinlelogun.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:20 ni o tọ