Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 21:12 BIBELI MIMỌ (BM)

ó lọ kó egungun Saulu, ati ti Jonatani, ọmọ rẹ̀, tí ó wà lọ́dọ̀ àwọn ará Jabeṣi-Gileadi. (Àwọn ará Jabeṣi ti jí àwọn egungun náà kó kúrò ní ìta gbangba, ní ààrin ìlú ní Beti Ṣani, níbi tí àwọn ará Filistia so wọ́n kọ́ sí, ní ọjọ́ tí wọ́n pa wọ́n ní òkè Giliboa.)

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:12 ni o tọ