Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 20:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá pe Abiṣai, ó ní, “Ìyọnu tí Ṣeba yóo kó bá wa yóo ju ti Absalomu lọ. Nítorí náà, kó àwọn eniyan mi lẹ́yìn kí o sì máa lépa rẹ̀ lọ. Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, ó lè gba àwọn ìlú olódi bíi mélòó kan kí ó sì dá wahala sílẹ̀ fún wa.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 20

Wo Samuẹli Keji 20:6 ni o tọ