Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 20:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu bá lọ sibẹ. Obinrin náà bèèrè pé, “Ṣé ìwọ ni Joabu?”Joabu dáhùn pé, “Èmi ni.”Obinrin náà ní, “Gbọ́ ọ̀rọ̀ tí èmi, iranṣẹbinrin rẹ fẹ́ sọ.”Joabu dá a lóhùn pé, “Mò ń gbọ́.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 20

Wo Samuẹli Keji 20:17 ni o tọ