Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Abineri ọmọ Neri, tíí ṣe balogun àwọn ọmọ ogun Saulu, gbé Iṣiboṣẹti ọmọ Saulu sá lọ sí Mahanaimu ní òdìkejì odò Jọdani.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:8 ni o tọ