Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 2:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu ati àwọn eniyan rẹ̀ bá gbé òkú Asaheli, wọ́n sì lọ sin ín sí ibojì ìdílé wọn ní Bẹtilẹhẹmu. Gbogbo òru ọjọ́ náà ni wọ́n fi rìn; ní òwúrọ̀ kutukutu ọjọ́ keji, ni wọ́n pada dé Heburoni.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:32 ni o tọ