Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Seruaya mẹtẹẹta, Joabu, Abiṣai, ati Asaheli, wà lójú ogun náà. Ẹsẹ̀ Asaheli yá nílẹ̀ pupọ, àfi bí ẹsẹ̀ àgbọ̀nrín.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:18 ni o tọ