Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Abineri bá sọ fún Joabu pé, “Jẹ́ kí àwọn bíi mélòó kan ninu àwọn ọmọkunrin láti ẹ̀gbẹ́ kinni keji bọ́ siwaju, kí wọ́n fi ohun ìjà dánrawò níwájú wa.”Joabu sì gbà bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:14 ni o tọ