Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 19:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìjà bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ẹ̀yà Israẹli káàkiri. Wọ́n ń wí láàrin ara wọn pé, “Ọba Dafidi ni ó gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, òun ni ó gbà wá lọ́wọ́ àwọn ará Filistia, ṣugbọn nisinsinyii, ó ti sá kúrò nílùú fún Absalomu.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:9 ni o tọ